سُنَّةَ ٱللَّهِ فِي ٱلَّذِينَ خَلَوۡاْ مِن قَبۡلُۖ وَلَن تَجِدَ لِسُنَّةِ ٱللَّهِ تَبۡدِيلٗا ٦٢
Sunnatallāhi fil-ladhīna khalaw min qablu walan tajida lisunnatillāhi tabdīlā
(Ó jẹ́) ìṣe Allāhu lórí àwọn tó ti lọ ṣíwájú.1 O ò sì níí rí ìyípadà kan fún ìṣe Allāhu.
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah al-Hijr; 15:13