44:26 وَزُرُوعٖ وَمَقَامٖ كَرِيمٖ ٢٦ Wazurū'in wamaqāmin karīm Àti àwọn irúgbìn pẹ̀lú àyè àpọ́nlé (tí wọ́n fi sílẹ̀).