Suratu Taha, aaya 67

20:67

فَأَوۡجَسَ فِي نَفۡسِهِۦ خِيفَةٗ مُّوسَىٰ ٦٧

Fa awjasa fī nafsihī khīfatam mūsā

Ìbẹ̀rù wọn sì mú (Ànábì) Mūsā.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Tàbí “(Ànábì) Mūsā pa ìbẹ̀rù wọn mọ́ra”.