Suratu Maryam, aaya 61

19:61

جَنَّٰتِ عَدۡنٍ ٱلَّتِي وَعَدَ ٱلرَّحۡمَٰنُ عِبَادَهُۥ بِٱلۡغَيۡبِۚ إِنَّهُۥ كَانَ وَعۡدُهُۥ مَأۡتِيّٗا ٦١

Jannāti 'adninil-latī wa'adar-rahmānu 'ibādahū bil-ghaybi innahū kāna wa'duhū ma'tiyyā

(Wọn yóò wọ inú) àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra gbére tí Àjọkẹ́-ayé ṣe ní àdéhùn ní ìkọ̀kọ̀1 fún àwọn ẹrúsìn Rẹ̀. Dájúdájú (Allāhu), àdéhùn Rẹ̀ ń bọ̀ wá ṣẹ.

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìyẹn ni pé, wọn kò lè fojú rí àdéhùn náà nílé ayé, àmọ́ òdodo ni, wọ́n sì máa rí i ṣójú ní Ọjọ́ Àjíǹde.