وَمَآ أَصَٰبَكُم مِّن مُّصِيبَةٖ فَبِمَا كَسَبَتۡ أَيۡدِيكُمۡ وَيَعۡفُواْ عَن كَثِيرٖ ٣٠
Wamā asābakum mim musībatin fabimā kasabat aydīkum waya'fū 'an kathīr
Ohunkóhun tí ó bá kàn yín nínú àdánwò, ohun tí ẹ fi ọwọ́ ara yín fà ni.1 Ó sì ń ṣàmójúkúrò níbi ọ̀pọ̀lọ́pọ̀.
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah an-Nisā’; 4:79.