Suratu Ash-Shu'ara, aaya 197

26:197

أَوَلَمۡ يَكُن لَّهُمۡ ءَايَةً أَن يَعۡلَمَهُۥ عُلَمَٰٓؤُاْ بَنِيٓ إِسۡرَٰٓءِيلَ ١٩٧

Awalam yakul lahum āyatan an ya'lamahū 'ulamā'u banī isrā'īl

Ṣé kò jẹ́ àmì kan fún wọn pé àwọn onímọ̀ (nínú) àwọn ọmọ ’Isrọ̄’īl nímọ̀ (sí àsọọ́lẹ̀ nípa) rẹ̀ (nínú tírà ọwọ́ wọn)?1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah Yūnus; 10:94.