Suratu Al-Isra, aaya 106

17:106

وَقُرۡءَانٗا فَرَقۡنَٰهُ لِتَقۡرَأَهُۥ عَلَى ٱلنَّاسِ عَلَىٰ مُكۡثٖ وَنَزَّلۡنَٰهُ تَنزِيلٗا ١٠٦

Waqur'ānan faraqnāhu litaqra'ahū 'alan-nāsi 'alā mukthin wanazzalnāhu tanzīlā

Àti pé al-Ƙur’ān, A ṣàlàyé rẹ̀ (fún ọ) nítorí kí o lè ké e fún àwọn ènìyàn pẹ̀lú pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́. A sì sọ̀ ọ́ kalẹ̀ díẹ̀ díẹ̀.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìyẹn láti inú sánmọ̀ ilé ayé wá sílé ayé.